Lyrics: Brymo – Omo mi owon

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Bàbá rẹ ò gbọ̀n tóó
Dáríjì mí o
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Kò sẹnì gbọn jù Ọlọ́run lọ
Ṣé bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Òrìṣà òkè
Oh, eh, Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọlú ọ̀run gan-an ò gbọ́n tó
Kò sí bo ṣe ṣe tó ma t’ènìyàn
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Kò s’ẹ́ni gbọ́n ju Ọlú ọ̀run lọ
Ṣe bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Bò n là kàkà
Àwọn alaálè
Wọn ò ní f’orí j’ọ̀ṣíká
A ò ṣè kà
A ò parọ́
A ò parọ́ o
Ah, a ma là
A ma là
A ma là


Posted

in

by

Comments

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.