Lyrics: Barry Jhay – Motide

Intro
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, mo ti de (Mo ti de)
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, mo ti de o
Gb’ọrọ mi ro, uh, gbe’ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o

Verse 1
Ogbigba ti n gba alailara
Ku igba gbogbo mi o
Iba ma ṣe pe mo ni Jesu ni Baba
Ọmọ araiye o ba joju mi
Eniyan sare ko le bajẹ ṣugbọn o, ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi

Pre-Chorus
Ọmọ, ṣe you know aanu ni mo ri gba lọdọ Yahweh?
O fun ọmọ araye laye lati bere pe “Ọlọrun mi da?”
Mo yege
Ori mi san’re, adura mi gba (Oh-ah)
When I call Am, He dey answer
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi

Chorus
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, motide
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, motide o
Gb’ọrọ mi ro, uh, gbe’ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o
Yea-yea, yea, yea-yea
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, mo de, sẹ
Ọba ti n gb’ẹkun aladura, moti de o
Gb’ọrọ mi ro, oh, gbe’ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o

Verse 2
Who can ta’ku laya?
Nobody, ta lo fẹ gbege ẹ si
Nobody reach to question You
You know You be the final say, kabiyesi o
Oh! When I had no one to call on
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi

Pre-Chorus
Ọmọ, ṣe you know aanu ni mo ri gba lọdọ Yahweh?
O fun ọmọ araye laye lati bere pe “Ọlọrun mi da?”
Mo yege
Ori mi san’re, adura mi gba
When I call Am, He dey answer
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi

Outro
Sunshine


Posted

in

by

Comments

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.